Joẹli 1:12 BM

12 Èso àjàrà ti rọ,igi ọ̀pọ̀tọ́ sì ti ń gbẹ.Igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ ati igi ápù, ati gbogbo àwọn igi eléso ti gbẹ,inú ọmọ eniyan kò sì dùn mọ́.

Ka pipe ipin Joẹli 1

Wo Joẹli 1:12 ni o tọ