Joẹli 1:3 BM

3 Ẹ sọ fún àwọn ọmọ yín nípa rẹ̀,kí àwọn náà sọ fún àwọn ọmọ wọn,kí àwọn ọmọ wọn sì sọ fún àwọn ọmọ tiwọn náà.

Ka pipe ipin Joẹli 1

Wo Joẹli 1:3 ni o tọ