Joẹli 2:21 BM

21 Má bẹ̀rù, ìwọ ilẹ̀,jẹ́ kí inú rẹ máa dùn,kí o sì máa yọ̀,nítorí OLUWA ti ṣe nǹkan ńlá.

Ka pipe ipin Joẹli 2

Wo Joẹli 2:21 ni o tọ