Joẹli 2:9 BM

9 Wọ́n ń gun odi ìlú,wọ́n ń sáré lórí odi.Wọ́n ń gun orí ilé wọlé,wọ́n gba ojú fèrèsé bẹ́ sinu ọ̀dẹ̀dẹ̀ bí olè.

Ka pipe ipin Joẹli 2

Wo Joẹli 2:9 ni o tọ