Nahumu 1:5 BM

5 Àwọn òkè ńláńlá mì tìtì níwájú rẹ̀,àwọn òkè kéékèèké sì yọ́.Ilẹ̀ di asán níwájú rẹ̀,ayé ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ di òfo.

Ka pipe ipin Nahumu 1

Wo Nahumu 1:5 ni o tọ