Nahumu 2:10 BM

10 A ti pa Ninefe run! Ó ti dahoro!Ọkàn àwọn eniyan ti dàrú,orúnkún wọn ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀,ìrora dé bá ọpọlọpọ,gbogbo ojú wọn sì rẹ̀wẹ̀sì.

Ka pipe ipin Nahumu 2

Wo Nahumu 2:10 ni o tọ