Nahumu 2:12 BM

12 Akọ kinniun a máa fa ẹran yafún àwọn ọmọ rẹ̀,a sì máa lọ́ ẹran lọ́rùn pafún àwọn abo rẹ̀;a máa kó ẹran tí ó bá paati èyí tí ó fàya sinu ihò rẹ̀.

Ka pipe ipin Nahumu 2

Wo Nahumu 2:12 ni o tọ