Nahumu 2:4 BM

4 Àwọn kẹ̀kẹ́ ogun ń dà wọ ìgboro pẹlu ariwo,wọ́n ń sáré sókè sódò ní gbàgede;wọ́n mọ́lẹ̀ yòò bí iná ìtùfù,wọ́n ń kọ mànà bí mànàmáná.

Ka pipe ipin Nahumu 2

Wo Nahumu 2:4 ni o tọ