Ọbadaya 1:2 BM

2 Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù;gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín.

Ka pipe ipin Ọbadaya 1

Wo Ọbadaya 1:2 ni o tọ