3 Ìgbéraga rẹ ti tàn ọ́ jẹ,ìwọ tí ò ń gbé inú pàlàpálá òkúta,tí ibùgbé rẹ wà lórí òkè gíga,tí o sì ń wí ninu ọkàn rẹ pé, ‘Ta ni ó lè fà mí lulẹ̀?’
Ka pipe ipin Ọbadaya 1
Wo Ọbadaya 1:3 ni o tọ