Rutu 2:1 BM

1 Ní àkókò yìí, ọkunrin ọlọ́rọ̀ kan wà ninu ìdílé Elimeleki, ẹbí kan náà ni ọkunrin yìí ati ọkọ Naomi. Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Boasi.

Ka pipe ipin Rutu 2

Wo Rutu 2:1 ni o tọ