Rutu 2:17 BM

17 Rutu bá tún bẹ̀rẹ̀ sí ṣa ọkà. Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, ó pa ọkà tí ó ṣà, ohun tí ó rí tó ìwọ̀n efa ọkà baali kan.

Ka pipe ipin Rutu 2

Wo Rutu 2:17 ni o tọ