Rutu 2:23 BM

23 Rutu bá ń bá àwọn ọmọbinrin Boasi lọ láti ṣa ọkà títí wọ́n fi parí ìkórè ọkà Baali, ó sì ń gbé ọ̀dọ̀ ìyá ọkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Rutu 2

Wo Rutu 2:23 ni o tọ