Rutu 3:16 BM

16 Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ ìyá ọkọ rẹ̀, ìyá ọkọ rẹ̀ bi í pé, “Báwo ni ibẹ̀ ti rí, ọmọ mi?”Rutu bá sọ gbogbo ohun tí ọkunrin náà ṣe fún un.

Ka pipe ipin Rutu 3

Wo Rutu 3:16 ni o tọ