Rutu 4:12 BM

12 Àwọn ọmọ tí OLUWA yóo jẹ́ kí obinrin yìí bí fún ọ yóo kún ilé rẹ fọ́fọ́, bí ọmọ ti kún ilé Peresi, tí Tamari bí fún Juda.”

Ka pipe ipin Rutu 4

Wo Rutu 4:12 ni o tọ