Sakaraya 1:11 BM

11 Wọ́n sì jíṣẹ́ fún angẹli OLUWA, tí ó dúró láàrin àwọn igi mitili náà pé, “A ti lọ rin ilẹ̀ ayé wò jákèjádò, a sì rí i pé wọ́n wà ní alaafia ati ìdákẹ́rọ́rọ́.”

Ka pipe ipin Sakaraya 1

Wo Sakaraya 1:11 ni o tọ