Sakaraya 1:12 BM

12 Angẹli OLUWA bá dáhùn pé, “OLUWA àwọn ọmọ ogun, yóo ti pẹ́ tó kí o tó yọ́nú sí Jerusalẹmu ati àwọn ìlú Juda, tí o tí ń bínú sí láti aadọrin ọdún sẹ́yìn?”

Ka pipe ipin Sakaraya 1

Wo Sakaraya 1:12 ni o tọ