Sakaraya 2:10 BM

10 OLUWA ní, “Ẹ kọrin ayọ̀, kí ẹ sì jẹ́ kí inú yín máa dùn, ẹ̀yin ará Jerusalẹmu, nítorí pé mò ń bọ̀ wá máa ba yín gbé.

Ka pipe ipin Sakaraya 2

Wo Sakaraya 2:10 ni o tọ