Sakaraya 2:9 BM

9 N óo bá àwọn ọ̀tá yín jà; wọn yóo sì di ẹrú àwọn tí ń sìn wọ́n.Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA àwọn ọmọ ogun.

Ka pipe ipin Sakaraya 2

Wo Sakaraya 2:9 ni o tọ