Sakaraya 5:7 BM

7 Nígbà tí wọ́n ṣí ìdérí òjé tí wọ́n fi bo agbọ̀n náà kúrò lórí rẹ̀, mo rí obinrin kan tí ó jókòó sinu eefa náà.

Ka pipe ipin Sakaraya 5

Wo Sakaraya 5:7 ni o tọ