Sakaraya 5:8 BM

8 Angẹli náà sọ pé “Ìwà ìkà ni obinrin yìí dúró fún.” Ó ti obinrin náà pada sinu agbọ̀n eefa náà, ó sì fi ìdérí òjé náà dé e mọ́ ibẹ̀ pada.

Ka pipe ipin Sakaraya 5

Wo Sakaraya 5:8 ni o tọ