Sakaraya 9:12 BM

12 Ẹ pada sí ibi ààbò yín,ẹ̀yin tí a kó lẹ́rú lọ tí ẹ sì ní ìrètí;mo ṣèlérí lónìí pé,n óo dá ibukun yín pada ní ìlọ́po meji.

Ka pipe ipin Sakaraya 9

Wo Sakaraya 9:12 ni o tọ