Efesu 2:17 BM

17 Nígbà tí ó dé, ó waasu ìyìn rere alaafia fún ẹ̀yin tí ẹ wà ní ọ̀nà jíjìn, ó sì waasu ìyìn rere alaafia fún àwọn tí ó wà nítòsí.

Ka pipe ipin Efesu 2

Wo Efesu 2:17 ni o tọ