Efesu 3:19 BM

19 kí ẹ lè mọ bí ìfẹ́ Kristi ti tayọ ìmọ̀ ẹ̀dá tó, kí ẹ sì lè kún fún gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Efesu 3

Wo Efesu 3:19 ni o tọ