Efesu 4:13 BM

13 Báyìí ni gbogbo wa yóo fi dé ìṣọ̀kan ninu igbagbọ ati ìmọ̀ Ọmọ Ọlọrun, tí a óo fi di géńdé, tí a óo fi dàgbà bí Kristi ti dàgbà.

Ka pipe ipin Efesu 4

Wo Efesu 4:13 ni o tọ