15 Ṣugbọn a óo máa sọ òtítọ́ pẹlu ìfẹ́, a óo máa dàgbà ninu rẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà, ninu Kristi tíí ṣe orí.
Ka pipe ipin Efesu 4
Wo Efesu 4:15 ni o tọ