Efesu 5:20 BM

20 Ẹ máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun Baba nígbà gbogbo fún gbogbo nǹkan ní orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi.

Ka pipe ipin Efesu 5

Wo Efesu 5:20 ni o tọ