3 Kí á má ṣe gbúròó ìwà àgbèrè, tabi oríṣìíríṣìí ìṣekúṣe, tabi ojúkòkòrò láàrin àwọn eniyan Ọlọrun.
Ka pipe ipin Efesu 5
Wo Efesu 5:3 ni o tọ