Galatia 6:10 BM

10 Nítorí náà, bí a bá ti ń rí ààyè kí á máa ṣe oore fún gbogbo eniyan, pàápàá fún àwọn ìdílé onigbagbọ.

Ka pipe ipin Galatia 6

Wo Galatia 6:10 ni o tọ