Galatia 6:9 BM

9 Kí á má ṣe jẹ́ kí ó sú wa láti ṣe rere, nítorí nígbà tí ó bá yá, a óo kórè rẹ̀, bí a kò bá jẹ́ kí ó rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Galatia 6

Wo Galatia 6:9 ni o tọ