Johanu Kinni 1:3 BM

3 Ohun tí a ti rí, tí a sì ti gbọ́ ni à ń kéde fun yín, kí ẹ lè ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu wa. Ìrẹ́pọ̀ yìí ni a ní pẹlu Baba ati pẹlu Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 1

Wo Johanu Kinni 1:3 ni o tọ