Johanu Kinni 2:3 BM

3 Ọ̀nà tí a fi lè mọ̀ pé a mọ Ọlọrun ni pé bí a bá ń pa àṣẹ rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 2

Wo Johanu Kinni 2:3 ni o tọ