Johanu Kinni 3:12 BM

12 Kí á má dàbí Kaini tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Èṣù, tí ó pa arakunrin rẹ̀. Kí ló dé tí ó fi pa á? Nítorí iṣẹ́ tirẹ̀ burú, ṣugbọn ti arakunrin rẹ̀ dára.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 3

Wo Johanu Kinni 3:12 ni o tọ