Johanu Kinni 4:17 BM

17 Nípa bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ ṣe di pípé ninu wa, kí á lè ní ìgboyà ní ọjọ́ ìdájọ́ pé bí ó ti rí ni àwa náà rí ninu ayé yìí.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 4

Wo Johanu Kinni 4:17 ni o tọ