Johanu Kinni 5:2 BM

2 Ọ̀nà tí a fi lè mọ̀ pé a fẹ́ràn àwọn ọmọ Ọlọrun ni pé kí á fẹ́ràn Ọlọrun kí á sì máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 5

Wo Johanu Kinni 5:2 ni o tọ