Johanu Kinni 5:9 BM

9 À ń gba ẹ̀rí eniyan, ṣugbọn ẹ̀rí Ọlọrun tóbi ju ti eniyan lọ; nítorí ẹ̀rí Ọlọrun ni, tí ó jẹ́ nípa Ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 5

Wo Johanu Kinni 5:9 ni o tọ