Johanu 10:15 BM

15 gẹ́gẹ́ bí Baba ti mọ̀ mí, tí èmi náà sì mọ Baba. Mo ṣetán láti kú nítorí àwọn aguntan.

Ka pipe ipin Johanu 10

Wo Johanu 10:15 ni o tọ