Johanu 10:16 BM

16 Mo tún ní àwọn aguntan mìíràn tí kò sí ninu agbo yìí. Mo níláti dà wọ́n wá. Wọn yóo gbọ́ ohùn mi. Wọn yóo wá di agbo kan lábẹ́ olùṣọ́-aguntan kan.

Ka pipe ipin Johanu 10

Wo Johanu 10:16 ni o tọ