Johanu 11:19 BM

19 Ọpọlọpọ ninu àwọn Juu ni wọ́n wá láti Jerusalẹmu sọ́dọ̀ Mata ati Maria láti tù wọ́n ninu nítorí ikú arakunrin wọn.

Ka pipe ipin Johanu 11

Wo Johanu 11:19 ni o tọ