Johanu 11:20 BM

20 Nígbà tí Mata gbọ́ pé Jesu ń bọ̀, ó jáde lọ pàdé rẹ̀. Ṣugbọn Maria jókòó ninu ilé.

Ka pipe ipin Johanu 11

Wo Johanu 11:20 ni o tọ