Johanu 19:26 BM

26 Nígbà tí Jesu rí ìyá rẹ̀ ati ọmọ-ẹ̀yìn tí ó fẹ́ràn tí wọ́n dúró, ó wí fún ìyá rẹ̀ pé, “Obinrin, wo ọmọ rẹ.”

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:26 ni o tọ