Johanu 19:27 BM

27 Ó bá sọ fún ọmọ-ẹ̀yìn náà pé, “Wo ìyá rẹ.” Láti ìgbà náà ni ọmọ-ẹ̀yìn náà ti mú ìyá Jesu lọ sílé ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:27 ni o tọ