Peteru Keji 2:7 BM

7 Ṣugbọn ó yọ Lọti tí ó jẹ́ olódodo eniyan, tí ọkàn rẹ̀ bàjẹ́ nítorí ìwàkiwà àwọn tí ń ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wọn.

Ka pipe ipin Peteru Keji 2

Wo Peteru Keji 2:7 ni o tọ