Peteru Keji 2:8 BM

8 Nítorí ohun tí ojú rẹ̀ ń rí ati ohun tí etí rẹ̀ ń gbọ́ ń ba ọkàn ọkunrin olódodo yìí jẹ́ lojoojumọ bí ó ti ń gbé ààrin àwọn eniyan burúkú yìí.

Ka pipe ipin Peteru Keji 2

Wo Peteru Keji 2:8 ni o tọ