Tẹsalonika Keji 1:3 BM

3 Ẹ̀yin ará, ó yẹ kí á máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun nígbà gbogbo nítorí yín. Ó tọ́ bẹ́ẹ̀ nítorí pé igbagbọ yín ń tóbi sí i, ìfẹ́ ẹnìkọ̀ọ̀kan yín sí ara yín sì ń pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 1

Wo Tẹsalonika Keji 1:3 ni o tọ