Tẹsalonika Keji 1:4 BM

4 Àwa fúnra wa ń fọ́nnu nípa yín láàrin àwọn ìjọ Ọlọrun. À ń ròyìn ìfaradà ati igbagbọ yín ninu gbogbo inúnibíni ati ìpọ́njú tí ẹ̀ ń faradà.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 1

Wo Tẹsalonika Keji 1:4 ni o tọ