Tẹsalonika Keji 2:10 BM

10 Yóo fi ọ̀nà àrékérekè burúkú lóríṣìíríṣìí tan àwọn ẹni ègbé jẹ, nítorí wọn kò ní ìfẹ́ òtítọ́, tí wọn ìbá fi rí ìgbàlà.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 2

Wo Tẹsalonika Keji 2:10 ni o tọ