Tẹsalonika Keji 2:9 BM

9 Nítorí Ẹni Burúkú yìí yóo farahàn pẹlu agbára Èṣù: yóo máa pidán, yóo ṣe iṣẹ́ àmì, yóo ṣe iṣẹ́ ìtànjẹ tí ó yani lẹ́nu.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 2

Wo Tẹsalonika Keji 2:9 ni o tọ