8 Nígbà tí ó bá kúrò lọ́nà tán ni Ọkunrin Burúkú nnì yóo wá farahàn. Ṣugbọn Oluwa Jesu yóo fi èémí ẹnu rẹ̀ pa á, yóo sọ ìfarahàn rẹ̀ di asán.
Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 2
Wo Tẹsalonika Keji 2:8 ni o tọ