2 Kí ẹ tún máa gbadura pé kí Ọlọrun gbà wá lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú ati àwọn ìkà, nítorí kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó gbàgbọ́.
Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 3
Wo Tẹsalonika Keji 3:2 ni o tọ